top of page

AA34:Akiyesi i. .......Ta nika? sebi Ara ni ika! /2.

Gbogbo eya ara wa lo ni ika tie;

oju nika

enu nika

imu nika

ahan nika

eti nika ati bebe lo.

Sugbon ika oju lo ga ju, buruju koda ogun hun be e pelu ki oluwa gba wa lowo ara wa tori awa ni ota ara wa mo she bi eyan eleran ara ni ka gbogbowa la lara gbogbo wa nika. IKANIANS ni wa.

gbogbo ara kiki ika.

Ese te e teti simi.

Aku apero o o o.

Ema shalai fi ero o yin han ninu comments o.

Thank you for listening and watching!

We are new SUBSCRIBE! LIKE! SHARE!

Do feel free to comment your take on today's call for Akiyesi i. Aku eto o o o.

bottom of page