ElO/4:- Listening ti Teti si awon omowa.Eti inu ni ejo hun lo o o atipe eti toba gbo alo oye ko gbo abo o o o. Listening to our children, creating and giving them the room to...
ElO/3:-praising/encouraging yiniyini.Yini yini keni o she mi i. Praising and encouraging our children being used as a tool often has a positive effect on them it boost their...
ElO/2:-giving instructions iranni nishe/jijishe.Giving instruction properly is an effective tool in positive parenting. its effective use brings a lot of peace and joy to the home...
EIO/1:- eye contact ojukoro.Irinshe fun ise obi ni shishe. parental tools to aid our positive parenting skills. Ese te e teti simi. Aku apero o o o. E ma shalai...
13:Oge grooming awon omo waShe efi oge shishe ko awon omo yin bi i? Hunje e ti mo pe oge shishe fun awon omo wa ko ju: wiwe dede,ka para dede,fonu dede,wo awotele...
2:IKINIHun je e hun ki awon omo yin karo bi i? Hunje awon naa ki i yin bi i? Do you as a parent greet your children good morning and vice...
12: OHUN ISO RO O WA A.Pele oni Ako oni Abo o o o. Hunje eti e mo pe eyin lohun bi i? Hunje e tie fi erosi ke to so ohun kohun? She le gba ki won bayin soro bi...
11:SHE AWON OMO YI TABILI YIN KA.Hunje ehun jehun po pelu awon omo yin bi i? Eje ka ma jeun po pelu awon omo wa. A family that eats together stays together. Ese te e teti...
8:Eko ìlè ise ìlè she Pataki oHunje eti e fi eko ile komo bi i? Hunje e eti e fi ise ile komo bi i? Abi she ni e ma hun so pe haa omo ilu oyinbo ni i? Ki ko ni mi mo o...
7: SISO EJO O ATI ESE E NIGBATI O TO NIGBATI O YE.Ojowo leti so ejo o pls ati ese thankyou gbeyin? She e ti e ma a so rara? Saying please and thankyou has and when due. E jeki a maa so...