intro:AitaleAbiamo
SHE TI RI GBO O O O B...L...O...G AITALE E E E ABIAMO O O O
LETO O O O.
To mo kin yin o o o.
Aku igbayi o o o.
Emi tiyin ni to o to o o o.
Aitale Abiamo.
Hello, everyone,
My BLOG is Aitale Abiamo.
Just my take, views and opinions about children, parenting, family, society
and our culture
Oro ishiti lori eko ile,asa ati isee wa.
Won ni Ile lati keso rode tori omo ti aba ko ni yio gbe ile ti aba ko ta.
Atipe omo eni lolani omo ni kara tori omolaso.
Ese te e teti simi.Aku apero o o o.
E ma shalai fi ero o yin han ninu comments o.
Thank you for listening and watching! SUBSCRIBE! LIKE! SHARE!
Do feel free to comment your take on today's call for Akiyesi i.
Aku eto o o o.